Thursday, October 10, 2013

ADURA HOUR (1) waa gbadura!! Wa pariwo tooooooooo!!, wa kigbe bi eni ti won fi kondo lu; Wa wipe !!**ASUU KINI MO SEEEE!!** fi aye ati eko mi sille--aduraaaaa!!! (2) wa fo soke bi eni ti asa (hawk) gbe visa e lo. lee meeje (7 times)!!, wa kigbe FAGGAE! Oya je ki ori e pe.........adura-- (3) waa pariwooo pankere ooooo!! ni igba meje !! Wa sope, oya wa na jonathan legba bi ole (thief)!!-----adura (4) haaaaaa asiko ti fe lootan (u better gbaadura ko ma ba gbadura)....wa kigbe OLORUN OOOOOOO!!!! Maje ki n fi arugbo ara se Convocation!!!!.....gbaladura----- MA FI ADURA YII SERE...... Jowo GBA pelu awe (fastng) ki o SEND re SI AWON ORE RE..... Oti dara Fun e Loruko Jesu.

No comments:

Post a Comment